LÍLO ÈDÈ YORÙBÁ FÚN ÌGBỌ́RA-ẸNI-YÉ ÀTI ÌFẸSẸ̀MÚLẸ̀ ÌDÀGBÀSÓKÈ ÀWÙJỌ (1): ÌṢÍPAYÁ OJÚṢE ÌGBÌMỌ̀ ÌJỌBA ÌBÍLẸ̀ NÍ ÌBÁMU PẸ̀LÚ ÒFIN ÌṢÀKÓSO ORÍLẸ̀ ÈDÈ NÀÌJÍRÍÀ TI ỌDÚN (1999). Ohun Àmúlò Pàtàkì fún Ìlàlọ́yẹ̀ Aráàlú fún Èrèdí Àtikópa wọn nínú Ìṣèjọba Tiwa-n-Tiwa ní àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ- Yorùbá: Èkìtì, Èkó, Kogi, Kwara, Ògùn, Oǹdó, Ọ̀ṣun, Ọ̀yọ́
(Using the Yorùbá language for promoting mutual understanding and sustainable social development (1): An exposition of the functions of the Local Government Councils according to the 1999 Constitution of the Federal Republic of Nigeria — A vital resource material for the education of the ordinary citizens with a view to enabling them to participate in democratic governance in the Yorùbá – speaking States of Èkìtì, Èkó, Kogi, Kwara, Ògùn, Oǹdó, Ọ̀ṣun, and Ọ̀yọ́)